Samuẹli Kinni 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Samuẹli wí fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Mo ti ṣe ohun tí ẹ ní kí n ṣe. Mo ti fi ẹnìkan jọba lórí yín.

Samuẹli Kinni 12

Samuẹli Kinni 12:1-7