Samuẹli Kinni 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn bá pada lọ sí Giligali, wọ́n sì fi Saulu jọba níwájú OLUWA. Wọ́n rú ẹbọ alaafia, Saulu ati àwọn ọmọ Israẹli sì jọ ṣe àjọyọ̀ ńlá.

Samuẹli Kinni 11

Samuẹli Kinni 11:11-15