Samuẹli Kinni 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Saulu dá wọn lóhùn pé, “A kò ní pa ẹnikẹ́ni lónìí, nítorí pé, òní ni ọjọ́ tí OLUWA gba Israẹli là.”

Samuẹli Kinni 11

Samuẹli Kinni 11:10-15