Samuẹli Kinni 11:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli bá bèèrè lọ́wọ́ Samuẹli pé, “Níbo ni àwọn tí wọ́n sọ pé kò yẹ kí Saulu jẹ ọba wa wà? Ẹ kó wọn jáde, kí á pa wọ́n.”

Samuẹli Kinni 11

Samuẹli Kinni 11:8-13