Samuẹli Keji 9:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní ọdọmọkunrin kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Mika. Gbogbo àwọn ará ilé Siba sì di iranṣẹ Mẹfiboṣẹti.

Samuẹli Keji 9

Samuẹli Keji 9:6-13