Siba dáhùn pé, gbogbo ohun tí ọba pa láṣẹ ni òun yóo ṣe.Mẹfiboṣẹti bá bẹ̀rẹ̀ sí jẹun lórí tabili ọba, gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan ninu àwọn ọmọ ọba.