Samuẹli Keji 7:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ rẹ yóo sì lókìkí títí lae, gbogbo eniyan ni yóo sì máa wí títí lae pé, OLUWA àwọn ọmọ ogun ni Ọlọrun Israẹli. O óo sì mú kí arọmọdọmọ mi wà níwájú rẹ títí laelae.

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:18-29