Samuẹli Keji 7:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ǹjẹ́ nisinsinyii, OLUWA Ọlọrun, jẹ́ kí ìlérí tí o ṣe nípa èmi ati arọmọdọmọ mi ṣẹ nígbà gbogbo, sì ṣe ohun tí o ti ṣèlérí pé o óo ṣe.

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:18-27