Samuẹli Keji 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn n kò ní káwọ́ ìfẹ́ ńlá mi kúrò lára rẹ̀, bí mo ti ká a kúrò lára Saulu, tí mo sì yọ ọ́ lóyè, kí n tó fi í jọba.

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:8-19