Samuẹli Keji 7:14 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo jẹ́ baba fún un, yóo sì jẹ́ ọmọ mi. Bí ó bá ṣẹ̀, n óo bá a wí, n óo sì jẹ ẹ́ níyà, bí baba ti í ṣe sí ọmọ rẹ̀.

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:13-17