Samuẹli Keji 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú bí Dafidi gidigidi nítorí pé OLUWA lu Usa pa. Láti ìgbà náà ni wọ́n ti ń pe ibẹ̀ ní Peresi Usa, títí di òní olónìí.

Samuẹli Keji 6

Samuẹli Keji 6:6-15