Samuẹli Keji 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú bí OLUWA sí Usa, OLUWA sì lù ú pa nítorí pé ó fi ọwọ́ kan àpótí ẹ̀rí náà. Usa kú sẹ́gbẹ̀ẹ́ àpótí ẹ̀rí náà.

Samuẹli Keji 6

Samuẹli Keji 6:3-9