Samuẹli Keji 6:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó rú ẹbọ tán, ó súre fún àwọn eniyan náà ní orúkọ OLUWA àwọn ọmọ ogun.

Samuẹli Keji 6

Samuẹli Keji 6:12-23