Samuẹli Keji 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí náà wọnú ìlú, wọ́n sì gbé e sí ààyè rẹ̀, ninu àgọ́ tí Dafidi ti kọ́ sílẹ̀ fún un. Dafidi sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia sí OLUWA.

Samuẹli Keji 6

Samuẹli Keji 6:12-20