Samuẹli Keji 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, Iṣiboṣẹti ọmọ Saulu fi ẹ̀sùn kan Abineri pé ó bá obinrin Saulu kan, tí wọn ń pè ní Risipa, ọmọ Aya, lòpọ̀.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:1-17