Samuẹli Keji 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò tí ogun wà láàrin àwọn eniyan Dafidi ati àwọn eniyan Saulu, agbára Abineri bẹ̀rẹ̀ sí pọ̀ sí i láàrin àwọn tí wọ́n wà lẹ́yìn Saulu.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:1-13