Samuẹli Keji 3:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bi àwọn iranṣẹ rẹ̀ pé, “Ṣé ẹ kò mọ̀ pé eniyan ńlá, ati alágbára kan ni ó ṣubú lónìí, ní ilẹ̀ Israẹli?”

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:35-39