Samuẹli Keji 3:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn eniyan Dafidi, ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ni ó hàn sí gbangba pé, ọba kò lọ́wọ́ ninu pípa tí wọ́n pa Abineri.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:29-39