Samuẹli Keji 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ekeji ni Kileabu, ọmọ Abigaili, opó Nabali, ará Kamẹli. Ẹkẹta ni Absalomu, ọmọ Maaka, ọmọ Talimai, ọba Geṣuri.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:1-13