Samuẹli Keji 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọkunrin mẹfa ni wọ́n bí fún Dafidi nígbà tí ó wà ní Heburoni. Aminoni tí ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Ahinoamu, ará Jesireeli, ni àkọ́bí.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:1-5