Samuẹli Keji 3:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Joabu kúrò lọ́dọ̀ Dafidi, ó ranṣẹ lọ pe Abineri, wọ́n sì dá a pada láti ibi kànga Sira, ṣugbọn Dafidi kò mọ nǹkankan nípa rẹ̀.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:24-31