Samuẹli Keji 3:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí o mọ̀ pé ó wá tàn ọ́ jẹ ni? Ó wá fi ọgbọ́n wádìí gbogbo ibi tí ò ń lọ, ati gbogbo ohun tí ò ń ṣe ni.”

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:20-34