Samuẹli Keji 24:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi pa àṣẹ OLUWA mọ́, ó sì lọ sí ibi ìpakà Arauna, gẹ́gẹ́ bí Gadi ti sọ fún un.

Samuẹli Keji 24

Samuẹli Keji 24:14-25