Samuẹli Keji 24:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà gan-an, Gadi tọ Dafidi lọ, ó sì wí fún un pé, “Lọ sí ibi ìpakà Arauna kí o sì tẹ́ pẹpẹ kan fún OLUWA níbẹ̀.”

Samuẹli Keji 24

Samuẹli Keji 24:9-25