Samuẹli Keji 23:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí yóo fọwọ́ kan ẹ̀gún gbọdọ̀ lo ohun èlò tí a fi irin ṣe tabi igi ọ̀kọ̀,láti fi wọ́n jóná patapata.”

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:1-16