Samuẹli Keji 23:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn tí wọn kò mọ Ọlọrundàbí igi ẹ̀gún tí a gbé sọnù,kò sí ẹni tí ó lè fi ọwọ́ lásán gbá wọn mú.

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:1-12