36. Igali, ọmọ Natani, ará Soba, Bani, ará Gadi;
37. Seleki, ará Amoni, Naharai, ará Beeroti, tí ó máa ń ru ihamọra Joabu, ọmọ Seruaya.
38. Ira ati Garebu, àwọn mejeeji jẹ́ ará Itiri;
39. ati Uraya, ará Hiti.Gbogbo àwọn tí wọ́n jẹ́ akọni ọmọ ogun náà jẹ́ mẹtadinlogoji.