Samuẹli Keji 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú tún bí OLUWA sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì ti Dafidi láti kó ìyọnu bá wọn. OLUWA wí fún un pé, lọ ka àwọn ọmọ Israẹli ati ti Juda.

Samuẹli Keji 24

Samuẹli Keji 24:1-8