Samuẹli Keji 23:36-38 BIBELI MIMỌ (BM)

36. Igali, ọmọ Natani, ará Soba, Bani, ará Gadi;

37. Seleki, ará Amoni, Naharai, ará Beeroti, tí ó máa ń ru ihamọra Joabu, ọmọ Seruaya.

38. Ira ati Garebu, àwọn mejeeji jẹ́ ará Itiri;

Samuẹli Keji 23