Samuẹli Keji 23:33-35 BIBELI MIMỌ (BM)

33. Ṣama, ará Harari, Ahiamu, ọmọ Ṣarari, ará Harari;

34. Elifeleti, ọmọ Ahasibai, ará Maaka, Eliamu, ọmọ Ahitofẹli, ará Gilo;

35. Hesiro, ará Kamẹli, Paarai, ará Abiti;

Samuẹli Keji 23