Samuẹli Keji 23:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn ilé fa Dafidi pupọ tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi wí pé, “Báwo ni ìbá ti dùn tó, kí ẹnìkan bu omi wá fún mi mu, láti inú kànga tí ó wà ní ẹnubodè Bẹtilẹhẹmu.”

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:11-19