Samuẹli Keji 23:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi wà ní orí òkè kan tí wọ́n mọ odi yípo, ọ̀wọ́ àwọn ọmọ ogun Filistini kan ti gba Bẹtilẹhẹmu, wọ́n sì wà níbẹ̀.

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:11-23