Samuẹli Keji 22:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA, ò máa ṣe olóòótọ́ sí gbogbo àwọn tí wọ́n bá hu ìwà òtítọ́ sí ọ;ò sì máa fi ara rẹ hàn bí aláìlẹ́bi, fún gbogbo àwọn tí kò ní ẹ̀bi.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:18-34