Samuẹli Keji 22:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ni OLUWA ṣe san án fún mi, gẹ́gẹ́ bí òdodo mi,ati gẹ́gẹ́ bí mo ti jẹ́ mímọ́ níwájú rẹ̀.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:15-27