Samuẹli Keji 21:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Òmìrán kan tí ń jẹ́ Iṣibibenobu, gbèrò láti pa Dafidi. Ọ̀kọ̀ Iṣibibenobu yìí wọ̀n tó ọọdunrun ṣekeli idẹ, ó sì so idà tuntun mọ́ ẹ̀gbẹ́.

Samuẹli Keji 21

Samuẹli Keji 21:11-22