Samuẹli Keji 21:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun mìíràn tún bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ará Filistia ati àwọn ọmọ Israẹli. Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ sì lọ bá àwọn ará Filistia jagun. Bí wọ́n ti ń jà, àárẹ̀ mú Dafidi.

Samuẹli Keji 21

Samuẹli Keji 21:13-22