Samuẹli Keji 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, àwọn ará Juda wá sí Heburoni, wọ́n fi òróró yan Dafidi ní ọba wọn. Nígbà tí Dafidi gbọ́ pé àwọn ará Jabeṣi Gileadi ni wọ́n sin òkú Saulu,

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:1-9