Samuẹli Keji 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó àwọn ọkunrin tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ pẹlu, ati gbogbo ìdílé wọn, wọ́n sì ń gbé àwọn ìlú tí wọ́n wà ní agbègbè Heburoni.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:1-4