Samuẹli Keji 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun yòókù láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini kó ara wọn jọ sẹ́yìn Abineri, wọ́n sì dúró káàkiri lórí òkè, pẹlu ìmúra ogun.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:16-30