Samuẹli Keji 2:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Joabu ati Abiṣai ń lé Abineri lọ, bí oòrùn ti ń lọ wọ̀, wọ́n dé ara òkè Ama tí ó wà níwájú Gia ní ọ̀nà aṣálẹ̀ Gibeoni.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:15-29