Samuẹli Keji 19:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba dọwọ́ bojú, ó ń sọkún, ó sì ń kígbe sókè pé, “Ọmọ mi! Absalomu, ọmọ mi! Absalomu, ọmọ mi!”

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:1-8