Samuẹli Keji 19:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun náà yọ́ wọ ìlú jẹ́ẹ́, bí ẹni pé wọ́n sá lójú ogun, tí ìtìjú sì mú wọn.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:1-5