Samuẹli Keji 19:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ni Dafidi ati gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ gòkè odò Jọdani. Ó kí Basilai, ó fi ẹnu kò ó ní ẹnu, ó sì súre fún un; Basilai bá pada sí ilé rẹ̀.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:34-43