Samuẹli Keji 19:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba dáhùn pé, “N óo máa mú Kimhamu lọ, ohunkohun tí ó bá sì bèèrè, ni n óo ṣe fún un.”

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:36-43