Samuẹli Keji 19:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Basilai dáhùn pé, “Ọjọ́ tí ó kù fún mi láyé kò pọ̀ mọ́, kí ni n óo tún máa bá kabiyesi lọ sí Jerusalẹmu fún?

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:25-38