Samuẹli Keji 19:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba wí fún un pé, “Bá mi kálọ sí Jerusalẹmu, n óo sì tọ́jú rẹ dáradára.”

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:29-39