Samuẹli Keji 19:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí kan náà, Ṣimei, ọmọ Gera, ará Bẹnjamini, láti ìlú Bahurimu, sáré lọ sí odò Jọdani láti pàdé Dafidi ọba pẹlu àwọn eniyan Juda.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:12-20