Samuẹli Keji 19:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọba ń pada bọ̀, àwọn eniyan Juda wá sí Giligali láti pàdé rẹ̀ ati láti mú un kọjá odò Jọdani.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:13-18