Samuẹli Keji 19:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ní kí wọ́n sọ fún Amasa pé, ẹbí òun ni Amasa; ati pé, láti ìgbà náà lọ, Amasa ni òun yóo fi ṣe balogun òun, dípò Joabu. Ó búra pé kí Ọlọrun pa òun bí òun kò bá ṣe bẹ́ẹ̀.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:9-19