Samuẹli Keji 19:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí ìbátan ọba ni yín, ẹ̀jẹ̀ kan náà sì ni yín? Kí ló dé tí ẹ fi níláti gbẹ́yìn ninu ètò àtidá ọba pada sí ààfin rẹ̀.”

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:2-20